HYMN 969

1.  MO ti ba Jesu lo s'ode

     Mo ti ba Jesu lo s'ode

     Esu d'ele ko ba mi n'ile

     Mo ti ba Jesu lo s’ode.


2.  Jesu Kristi wa pelu mi

     Jesu Kristi wa pelu mi

     Orunko Re l’alye mo mi mo

     Jesu Kristi wa pelu mi.


3.  Monlo s’ijo Celestial

     Monlo s’ijo Celestial

     Egberun ljo sa lo mbe laiye

     Monlo s’ijo Celestial.


4.  O ti d’oju t’awon aje

     O ti d’oju ti awon aje

     Jesu Kristi lo da mi lare

     O ti d’oju t’awon oso.  Amin


English »

Update Hymn