HYMN 968

1.  JESU awa de s’inu ile Re

     Gb’owo Re le wa

     Kosi bukun fun wa.


2.  Alaimo ni wa

     Oba imole

     Dari ese ji wa

     Ko si se wa l’ogo.


3.  Jesu awa de

     pel'aimo wa

     Dari ese ji wa

     Ko si bukun fun wa.  Amin

English »

Update Hymn