HYMN 965

1.  BABA segun fun wa,

     Omo segun fun wa,

     Jesu Kristi Oluwa Oba anu,

     Segun fun wa k’oro wa d’ayo.


2.  Baba gb’ase wa se,

     Omo gba’se wa se,

     Jesu Mimo, Oluwa Oba anu,

     Gba’se wa se,

     K'oro wa d’ayo.


3.  Baba wa wo wa san,

     Omo wa wo wa san,

     Jesu Mimo, Oluwa Oba anu,

     Wa wo wa san,

     K'oro wa d'ayo.


4.  Baba gb'adura wa,

     Omo, gb'adura wa,

     Jesu Mimo, Oluwa Oba anu,

     Gb'adura wa k'oro wa dayo.


5.  Baba d’abo bo wa

     Omo d'abo bo wa 

     Jesu Mimo, Oluwa

     D’abo bo wa, k oro wa d'ayo.


6.  Baba fun wa l’agbara

     Omo fun wa l'agbara

     Jesu Mimo, Oluwa Oba anu

     Fun wa l’agbara

     K’oro wa d’ayo.


7.  Baba bukun fun wa

     Omo bukun fun wa

     Jesu Mimo, Oluwa Oba anu

     Wa bukun wa, k'oro

     wa d'ayo.  Amen


English »

Update Hymn