1. SEGUN fun wa, Baba segun fun wa, Segun fun wa, Baba segun fun wa, Ire ni Oluwa, Ire ni Oluwa, Baba Segun fun wa. 2. Wa wo wa san, Baba wa wo wa san, Wa wo wa san, Baba wa wo wa san, Ire ni Oluwa, Ire ni Oluwa, Baba wa wo wa san. 3. Gbase wa se, Baba gbase wa se, Gbase wa se, Baba gbase wa se, Ire ni Oluwa, Ire ni Oluwa Baba gbase wa se. 4. Wa bukun wa, Baba wa bukun wa Wa bukun wa, Baba wa bukun wa Ire ni Oluwa, Ire ni Oluwa Baba wa bukun wa. Amin