1. WA segun fun mi Jesu, Wa segun fun mi, Ire l'Oba to segun fun Dafidi, Wa segun fun mi. 2. Wa gba wa la Jesu Wa gba wa la Ire l’Oba to gba Daniel la wa gba. Amin