MO TI gba Jesu l’Oba t’emi
Jesu l’Oba to dara ju
Okan mi simi le Jesu o
Ko ni je k’oju ti mi.
Chorus: Ninu aiye mi o
Ko ni je k'oju ti mi
Ninu ijo Re
Ko ni je k’oju ti mi
Laarin Ebi mi o
Ko ni je k’oju ti mi
Laarin ota mi o
Ko ni je k'oju ti mi. Amin