HYMN 945

BABA wa to loko ti nwoka Re,

Oti mo pemo wa ninu oko,

Baba wa to loko ti nwako Re,

O ti mo pe mo wa ninu oko.

Solo: Ma se jeje ma wa walo

Chorus: Baba mi

Solo: Ma sejek’oko yi wo’gbo

Chorus: Baba mi

Solo: ma seje k’oko yi danu,

Chorus: Baba mi

Solo: Sin wa dele ologo yi o.

Chorus: Baba mi.  Amin


English »

Update Hymn