HYMN 938

1.  JESU ni ayo mi

     Jesu ni ayo mi

     Ayo t’aiye ko le f’owo

     bo, Jesu ni ayo mi


2.  Ayo otito ni

     Ayo ododo ni

     Ayo aiyeraiye ni t’emi

     Jesu ni ayo mi.  Amin


English »

Update Hymn