HYMN 909

Ka lo si Bethlehem

Ta ti bi jesu

Ka lo si Bethlehem

Ta ti bi jesu. 

Awon irawo orun

Nwon bu si ayo 

Awon irawo orun

Nwon bu si ayo.

S’olugbala to wa

Lati ko ese aiye lo 

S’olugbala to wa

Lati ko ese aiye lo.  Amin


English »

Update Hymn