E WO ona otito t’emi la sile, E wo ona iye yi ti mo pe nyin si, Egbe agbelebu, egbe agbelebu, E tan ‘mole sinu okunkun aiye, K’aiye k’aiye le mo p’Emi l’Oba ogo. Amin