1. Maria, Iya Mimo, Ire ni gbekele wa, Ran wa lowo, d’abo bo wa, Nitori Ogo Re. 2. Jesu Kristi Omo Olorun Se ‘re ni gbekele wa, Ran wa lowo, d’abo bo wa Nitori Ogo Re. 3. Holy Michael, ajagun segun, Se ‘re ni gbekele wa, Ran wa lowo, gbeja wa ja, Nitori Ogo re. Amin