HYMN 812

TETE tete da mi lohun

Oluwa mi,

Tete tete da mi lohun
Oluwa mi,

Bi mo ba kepe O ni

koko ni yewu,

Wa ran mi lowo lasikoh

yi Oba mi,

Ire nikan sa mo gbekele,

Oluwa mi.  Amin


English »

Update Hymn