1. ESIN Olorun, Esin Olorun, Oba Imole araiye, Didan ninu gbogbo ogo. 2. E mura lati sin Oluwa ninu ijo Mimo, Aiyeraye Oba Imole, Yio gba wa n'u gbekun aiye. 3. E je k'a sin Olorun E je k'a sin Olorun Aiyeraye Oba Imole Yio wa pelu wa loni. Amin