1. BABA Omo, emi Mimo, Ire Oluwa yio lo wa towo tese e, Ire Baba lo pe wa, T’awa je ipe Re. 2. Jesu Kristi mbo wa, Lati se ‘dajo aiye, Michael Oga Ogun na, Yio gesin na waiye. 3. Ida meje lowo, Oko mbe niha won, Esin yio te ema pa, Igba ikehin na ti de. Amin