1. WA gba wa la, Baba gba wa la, Wa gba wa la, Baba gba wa la, Ire ni Oluwa, Ire ni Oluwa, Baba wa gba wa la. 2. Segun fun wa, Baba segun fun wa, Segun fun wa, Baba segun fun wa, Ire ni Oluwa, Ire ni Oluwa, Baba segun fun wa. 3. Dabobo bo wa, Baba dabo bo wa, Dabo bo wa, Ire ni Oluwa, Ire ni Oluwa Baba dabo bo wa. 4. Wa bukun wa, Baba wa bukun wa, Wa bukun wa, Baba wa bukun wa, Ire ni Oluwa, Ire ni Oluwa. Baba wa bukun wa. Amin