HYMN 802

1.  BA WA tunse Baba,

     Ba wa tunse, Omo.

Chorus: Jesu Mimo Oluwa

        Oba Anu,

        Ba wa tunse ki ti

        wa dayo.


2.  Wa wo wa san,

     Baba wa wo wa san

     Omo wa wo wa san.

Chorus: Jesu Mimo Oluwa

        Oba Anu...


3.  Wa gbe wa ga,

     Baba, wa gbe wa ga,

     Omo wa gbe wa ga.

Chorus: Jesu Mimo Oluwa

        Oba Anu...


4.  Segun fun wa,

     Baba segun fun wa,

     Omo segun fun wa.

Chorus: Jesu Mimo Oluwa

        Oba Anu...


5.  Dabo bo wa,

     Baba dabo bo wa,

     Omo dabo bo wa.

Chorus: Jesu Mimo Oluwa

        Oba Anu...


6.  Pese funwa,

     Baba pese fun wa,

     Omo pese funwa.

Chorus: Jesu Mimo Oluwa

        Oba Anu...  Amen

English »

Update Hymn