1. Ara e, ba mi kalo, Ilekun anu si sile, Alabaro kan ko si, A fi Jesu nikan. 2. Ohun lo nsohun gbogbo, On pese fun aini wa, Nigbati adanwo ba de, On lo nsamona wa. Amin