HYMN 8

1.	Jesu l’onpe o tantan,

	Mabo elese wa,

	Jesu yio gbadura fun O

	Elese wa,

	Jesu konije k’oju ti o

	Elese wa

	Jesu konije k’oju ti o

	Elese wa.

2.	Eru re wiwo onpe o ma bo

	Elese wa,

	Jesu yio so eru na kale,

	Elese wa,

	Loni lo ye ko f’okan re fun

	Elese wa

	Loni lo ye ko f’okan re fun

	Elese wa.	Amin 

English »

Update Hymn