1. BABA wa ti mbe larin wa, Mase je k’oju ti wa, Owo Re lo da wa si, Wa pelu wa dopin. 2. EmiOrun sokale wa, Kowa ba wa sise, Awon to fara sile, Yio ri ‘ye lojo na. 3. Ilekun anu si sile, F’awon t’a f’ore ofe pe Sise ko le r’orun wo, Ere re mbe nibe. 4. Ojo ayo na ti de, Olugbala wole de, Awon Angeli kun f’ayo, F’ojo ‘kehin nla na. Amin