HYMN 791

1.  JEHOVAH Elyon Oluwa wa,

    Gbe waga larin Ijo Mimo.


2.  Wo Oba wa lori Ite Re,

     Fi ifegbo igbe Ijo Re.


3.  Wo Oluso Aguntan Re e,

     Pa agbo agutan Re mo.


4.  Wa gba wa larin ikoko aiye,

     Tan lmole Re sokunkun wa.


5.  Jesu wa ba Ijo Re gbe,

     Tu Emi Mimo Re s’okan wa.  Amin

English »

Update Hymn