1. Ka sowo po, ka sowo po Pelu ife Mimo Ka gbadura nigba gbogbo Ka teriba fun Oba Oluwa, E ma we owo fun ara nyin Pelu ’dapo Mimo. 2. E ma mura ninu ohun kan, Ijo kan Mimo ni, Ki ise pelu igberaga, Eda aiye ko dara E ma teriba fun ara nyin Iteriba Mimo. 3. E ma se soro ibunu, Ero buburu ko da Ijo Mimo ninu ife ni, E sin Oluwa pelu ife, Pelu ife l’awon Angeli Fi sin Baba l’Orun. Amin