HYMN 772
1. Ojo na pe loni Ijo Mimo,
Chorus: Ro dju, Ijo Mimo,
Bawo lo ti wa di okan re si,
Jowo, ro daju Ijo Mimo,
Eje Kristi Jesu iyebiye
To mu irapada wa f’araiye
F’eni to ba gbagbo to se gboran
Yio ri ‘ye ’Jo Mimo.
2. Iwo ha je’ele tabe letan?
Chorus: Ro dju, Ijo Mimo,
Bawo lo ti wa di okan re si,
Jowo, ro daju Ijo Mimo,
Eje Kristi Jesu iyebiye
To mu irapada wa f’araiye
F’eni to ba gbagbo to se gboran
Yio ri ‘ye ’Jo Mimo.
3. Ojukokoro ha ndamu re bi?
Chorus: Ro dju, Ijo Mimo,
Bawo lo ti wa di okan re si,
Jowo, ro daju Ijo Mimo,
Eje Kristi Jesu iyebiye
To mu irapada wa f’araiye
F’eni to ba gbagbo to se gboran
Yio ri ‘ye ’Jo Mimo.
4. Ikunsinu kan ha wa lokan re?
Chorus: Ro dju, Ijo Mimo,
Bawo lo ti wa di okan re si,
Jowo, ro daju Ijo Mimo,
Eje Kristi Jesu iyebiye
To mu irapada wa f’araiye
F’eni to ba gbagbo to se gboran
Yio ri ‘ye ’Jo Mimo.
5. Iwo ha le fi ise re sin Jesu?
Chorus: Ro dju, Ijo Mimo,
Bawo lo ti wa di okan re si,
Jowo, ro daju Ijo Mimo,
Eje Kristi Jesu iyebiye
To mu irapada wa f’araiye
F’eni to ba gbagbo to se gboran
Yio ri ‘ye ’Jo Mimo. Amin
English »Update Hymn