ENYIN ara ninu Kristi, E gbe orin soke, K’esi gbo ohun ti, Jehovah nso, Ere di re t’e fi wa Ninu Ijo Mimo yi? Ere di re t’e’fiwa? Ninu egbe nla yi? Ki Maria Iya wa, Le e wa sin wa lo, K’eni Mimo rere yi, Wa ma sin wa lo. Amin