1. O femi pupo Olorun mi,
Ju bi mo mo o to,
O femi pupo Olorun mi
Bi mo ti nife Re,
Halleluya.
2. Mo fe O pupo Olorun mi,
Ju fadaka a,
Mo fe O pupo Olorun mi,
Ju wura lo, Halleluya.
3. Bi mo ti nife Re,
Olorun mi, femi ju be lo o,
Bi mo ti nife Re,
Olorun mi, femi ju be lo,
Halleluya. Amin