HYMN 74
1. Eyo, e yo, e yo
Enyin omo ‘Jo Mimo
Ayo ni Baba wa,
E yo, e yo, e yo.
2. E mura sesin yi,
Enyin omo ‘Jo Mimo
Esin yi yio bori,
E yo, e yo, e yo.
3. Igba ‘kehin na de,
Enyin omo ‘Jo Mimo,
E di Oluwa mu,
E yo, e yo, e yo.
4. Aiye yi le sin wa,
Enyin omo ‘Jo Mimo,
E mura sesin yi,
Ke ba le ri Baba
E yo, e yo, e yo.
5. Ajinde ni Baba,
Baba wa orun wa,
Ologo meta ni,
E yo, e yo, e yo.
6. Ninu ayo lawa wa,
Awa Maleka Orun
Ayo ninu Kristi,
Ayo, ayo, ayo.
7. Awon agutan Jesu,
E si ‘se Baba nyin,
ayo yin yio si po,
ninu Kristi Jesu.
8. Ijo Mimo Orun,
T’aiye ‘yio gba aiye la,
E si ‘se Oluwa,
K’aguntan le po si
9. E f’ogo f’Oluwa,
Enyin omo ‘Jo Mimo,
Ogo ni fun Baba,
Ogo, Ogo, Ogo. Amin
English »Update Hymn