HYMN 736

1.	Jesu fe mi mo mo be,

	Jesu fe mi mo mo be,

	Halleluya lorin wa,

	A o f’ogo g’Olorun. 


2.	Iye ni f’eni to gbo,

	Iye ni f’eni to gbo,

	Ibukun f’oju to ri,

	P’Olugbala w ambo.  Amin



English »

Update Hymn