HYMN 732

A palase lagbala Orun,

Pe ki Ijo yi ma bi si,

A palase lagbala Orun,

Pe ko si ma re si

Titi gbogbo iponju aiye

Yio fi tan an laiye,

Titi Jesu Olugbala

Yio fi pada wa.  Amin


English »

Update Hymn