1. E mura ke sin ni ‘jo yi, Ijo mimo kan ni Ijo eleyi ni yio wa, titi aiyeraiye Cr: E foribale fun, E foribale fun, E foribale fun Baba, Oba awon oba. 2. E mura ke sin mi ‘jo yi, Ka le ye nikehin, E foribale fun Baba, Oba awon oba, Cr: E foribale fun, E foribale fun, E foribale fun Baba, Oba awon oba. 3. Ayo, Ayo, yio po, Ninu Ijo Mimo yi, Ijo yi ni yio gbaiyela, L’ojo mimo t’awi Cr: E foribale fun, E foribale fun, E foribale fun Baba, Oba awon oba. Amin