1. IMOLE, Imole, eyi t’owuro
Eyi t’owuro, o tan si asale.
Chorus: Halleluya, Halleluya
Ijo Mimo,
Eyo, ‘mole na ni 'jo yi.
2. Irawo, Irawo eyi t'owuro,
Eyi t’owuro mole si asale.
Chorus: Halleluya, Halleluya
Ijo Mimo,
Eyo, ‘mole na ni 'jo yi.
3. Gbogb’ aiye, gbogb’ aiye,
E kun fun ayo fun ‘Jo
ikehin yi,
Halleluya, Halleluya.
Chorus: Ijo 'kehin bori,
Halleluyah f’Oba. Amin