1. ONA to lo s’odo Olorun, Ona igbala ni, E ya ona na si mimo, Ona ibi iye. 2. Ibujoko ile aiye yi, Ibujoko asan, Ibujoko ti ko lopin, O wa lodo Jesu. Amin