1. JESU l’onpe wa,
Jesu l’ onpe wa,
Jesu l’onpe wa,
Ki awa soda Re.
2. Gbe agbara wo,
Gbe agbara wo,
Gbe agbara wo,
Ki a si r’Ogo Re.
3. Emi ni ti ‘Re,
Mimo ni ti ‘Re,
Iye ni ti Re,
Gbala mbe lowo Re. Amin