HYMN 678
1. GBOGBO aiye,e wa
wogo didan na,
Ti tan sori ljo Mimo,
Gbogbo aiye, a wa teriba,
Labe Ogo didan yi.
2. Aiye, e wa wo aye te wa,
E wa gbo ipe didan wa,
Ti ndun kikan,
ti ndun kikan pe,
Aiye, aiye, e sunmo Mi.
3. Te bale wa sodo Mi,
Ere yin mbe loke Orun,
Ere wura ati fadaka
ko eyi,
Ere ti ko lopin ni.
4. Eje ki gbogbo aiye teriba,
F'Oba Oluwa mi,
Eniti nse Olurapada okan,
Oba Alase.
5. Enyin aiye, e wa gbo ipe na,
Ti ndun kika-kikan,
L’Oke Orun
Enyin aiye, e wa sodo Mi. Amin
English »Update Hymn