1. Gbo bi ipe na ti n dun lorun Jesu duro ni bode orun Lati ko awon ayanfe Re Lo si ori ite Baba 2. Awon Angeli kun fayo Nwon nfun fere pelu ayo, Baba ka mi mo awon eyi, Ki nle ri Jesu lojo na. 3. Ore-ofe Re Baba la ntoro Agbara ati imisi Orun Ko wa ba wag be e lojo oni, K’Alleluya le je orin wa. Amin