A wa siwaju re loni, Baba wa Orun, Silekun anu Re sile, F’awa iranse Re, Silekun anu Re sile, F’awa iranse Re, Ran Maleka Ajagunsegun Ode orun si wa o, Boju anu Re wo wa o, Awa nkepe O, Boju anu Re wo wa o, Awa nkepe O. Amin