HYMN 636

1.  OLUSO Agutan, Oluso, Agutan,

     Akigbe tantan si yin,

     Wipe e yi pada si mi.


2.  Ipe anu ni eyi,

     T’aiye si npe yin Agutan,

     Olugbala lo npe yin,

     Wipe e yi pada si mi.


3.  Ijo Mimo, Emura,

     Fun ‘se nla, mo gbe fun yin,

     Eyi ni amure yin,

     Ti mo t i pese le e fun yin.


4.  Ijo Mimo, e wa gbo,

     Ti mo npe tantan si yin,

     Ojo ‘kehin na de tan,

     Ke le kun u aiye yin.  Amin

English »

Update Hymn