1. IMOLE didan na on lode yi, Imole didan na on lode yi, Enikeni to lemi Re lo le ri ogo na. 2. Apata aiyeraiye, on na ni Oluwa, Apata aiyeraiye, on na ni Oluwa, Enito ba si lemi Re, on na lo le mo. 3. Ijo Mimo, Etunra di, Edi amure yin, Ijo Mimo, e tunra di, e di amure yin, Olugbala lo si mbo wa lati se idajo. Amin