1. Maleka Mimo t’orun, Nwon ti t’Orun sokale, Lati wa sure fun wa, Ninu ijo Mimo 2. Enyin omo ijo Mimo Mura lati se ife Re Nitori o mbo Kankan Lati be wa wo. 3. Gbogbo ‘enyin Oluponju, E korin ke ho f’ayo Nitori oluwa mbo Yio da yin nide. 4. Ayo wa yio ti po to Nikehin ni ijoba Oruun Bi awa ba le mura S’ise Oluwa. 5. Enyin o sise Oluwa Mura lati sise na Nitori ere nyin po Li oke Orun. Amin