1. JI, arakunrin ji,
Fun se re ti O ko ise,
Ki ‘wo le ri ere re gba
lojo kehin.
2. Beru arakunrin beru,
Imole na ti de fun o,
Ki ‘wo le tan mole,
Larin okunkun aiye.
3. Sise arakunrin sise,
Ododo na ti de fun o,
K’iwo le so ododo
koju ti esu. Amin