HYMN 615

1.  ARA wakati na de,

     Lati se opo ise,

     Kale bori ‘nu ona wa,

     Olorun pelu wa.


2.  Ara tepa mo ‘se re,

    Lepa ipinu rere,

    Iru eyi t’enikan ko ise,

    Eyi logo wa,

    Eyi ni ‘bukun wa.  Amin


English »

Update Hymn