1. Ijinle ise l’Oluwa ran, T’awon Angeli wa je fun wa, K’agba ‘jo f’etisile ke gbo, K’agba ‘jo f’etisile ke gbo, Satani di Amure, Satani di Amure, Isegun kan ko si fun esu, Isegun kan ko si fun esu, 2. Ma beru sa ju Oluwa sile, Di imole ‘gbala yi mu, Sise pelu ife mimo, Sise pelu ife mimo, Ade iye yio je ti wa, Ade iye yio je ti wa, Halleluya lorin wa yio je, Halleluya lorin wa yio je. Amin