HYMN 605

1.	Ka sowopo ka joyin Baba,

	Ka sowopo ka joyin Baba,

	Fun ‘jo ikehin to sokale,

	Ke Hossanah, Ko Hossanah,

	So Olorun meta lokan. 


2.	Wa gba adura Olujo Mimo,

	Wa gba adura Olujo Mimo,

	Fun ‘jo kehin to sokale,

	Ke Hossanah, Ko Hossanah,

	So Olorun meta lokan.


3.	Wa gba wa la, Olujo Mimo,

	Wa gba wa la, Olujo Mimo,

	Fun ‘jo kehin to sokale,

	Ke Hossanah, ko Hossanah,

	So Olorun meta lokan.


4.	Wa bukun wa, Olujo Mimo,

	Wa bukun wa Olujo Mimo,

	Fun ‘jo kehin to sokale,

	Ke Hossanah, ko Hossanah,

	So Olorun meta lokan.


5.	Wa gbe wa ga, Olujo Mimo,

	Wa gbe wag a Olujo Mimo,

	Fun ‘jo kehin to sokale,

	Ke Hossanah, ko Hossanah,

	So Olorun meta lokan.  Amin

English »

Update Hymn