1. RlRO ni t'omo araiye, Enyin iranse Mi, Tujuka ke ‘tera mo ‘se Mi. 2. Enyin olusin otito, Otito ni ‘se Mi, Eni to ba s’otito yio mo. 3. Igba ‘kehin na sunmo le, Enyin ojise Mi, E mura ke le wo ipo yin l’orun. 4. Ise otito ati ife, Ni Baba l’orun fe, Enyin to ba si s’otito yio mo. 5. Oluwa Oba igbala, Yio gba awon ti ‘Re la, Awon to ba si p'ofin mo yio la. 6. Iye ainipekun yio wa, F’awon onise re, E mura ke si s'otito aiye. Amin