HYMN 601

1.  ISE aiye yi lo sopin,

     Ise aiye osi yi,

     E je ka gba Oluwa gbo,

     Ka le gbade iye.


2.  Ise Oluwa Iyanu,

     Eje ka mura si,

     Ise Oluwa Ogo ni,

     Ka le nibugbe loke.  Amin


English »

Update Hymn