1. Gbohun mi, gbohun mi, Tani mo ni laiye osi yi? Nigbati ’re ba ko mi sile Tani yio wa gba mi? 2. Tani yio samona mi? Ninu irin ajo mi, Ire ni Irawo didan owuro, Nigba t’ara ba ko mi sile Jesu yio wa gba mi. Amin.