Halleluya lat’Orun wa, Pelu orin ayo, Olugbala yio pada wa, Lai ko ni ireti E f’ogo f’Oluwa, E f’ogo f’Oluwa Awon Angeli kun f’ayo pelu iyin. Amin