1. NIGBATI fere badun l’Orun,
Nigbati fere badun l’Orun,
Nigbati fere badun l’Orun,
Nigbati fere badun, Mowa nibe.
2. Enyin Olurapada,
E o korin titi aiye,
Ko ni re yin,
Nigbati fere badun l’Orun,
Mo wa nibe
Nigbati fere badun l’Orun,
Nigbati fere badun,
Mo wa nibe. Amin