1. Baba ka mi mo won, Ki n le j’ogun iye, Ka mi mo awon ti orun Ki n le j’ogun iye. 2. Se mi ni ayanfe, Ki n le j’ogun iye Baba se mi ni ayanfe Ki n le j’ogun iye. 3. Enyin Ijo Mimo Oko ‘kehin l’eyi E mura giri lekoko K’oko ‘kehin to kun 4. Enyin ayanfe mi, E yin Mi lotito E mura giri lati sin Ke le j’ogun iye 5. Or’ofe Re Baba Ko ba w’omo Re gbe K’emi olutunu orun Ko ma s’amona wa. Amin