HYMN 553

1.	Onidajo aiye fere de,

	Jesu Oluwa wa o mbo wa o

	B’ode losan tabi loganjo,

	Nibo l’eyin o kese yin gba.


2.	Ijo Mimo, e bu si ayo,

	F’ojo Idajo na to ma de o,

	Opo lape die la o ri,

	Halle-Halleluyah lojo na.


3.	Celestial Church, idajo de o,

	Aje, Oso idajo de o,

	Pansaga ati agbere

	Nibo l’eyin o kese yin gba.  Amin

English »

Update Hymn