1. Baba mi, Olorun mi,
Mo fi ‘rele sunmo O
Jeki ‘rayo mu re ‘le
Oba mi Olurun mi.
2. Mo fi ‘gbagbo bere
Ogo nla la t’Orun wa
Igbagbo ti ko mikan
Ti ko je siye meji.
3. Emi Orun s’okale
Ko wa fun wa lagbara
Kaiye le mo daju pe
Ire ni Olorun wa. Amin