1. Mo ti sina sinu ese,
Ore Oluwa lori mi he,
Oku fun mi lori igi,
Ore Ofe Oga Ogo poju.
2. Mo ti sonu sinu ese,
Ore Oluwa lori mi he,
O ku fun mi lori igi,
Ore Ofe, Oga Ogo poju.
3. Halluya, Halleluya,
Ore Oluwa lori mi he,
O ku fun mi lori igi,
Ore Ofe, Oga Ogo poju. Amin